Luc 19,1-10

IWÉ LUKU, ÉWO 19: 1-10

SAKÉU PADÉ JÉSU

1 Jésu wϙ ilu Jériko lϙ, á la igboo kϙja

2 Bẹn’ϙkϙnin yé gbo aya á pé ni Sakéu, ϙgan a gba lampo ya, a wo kϙma ésini Jésu

3 Ama kotiko ri. N’di n’onian ya pϙ, n’di n’onian pukulu n’ϙwa

4 Osué lϙ liwaju, n’ologu égi sikomoré kan ni kofu ri n’di ni m’bẹ ni n’kϙ gba kϙja

5 Yé Jésu dé lϙ gan-gan ẹ ẹ, ϙgbin oju loké n’ϙfϙfύ ni : Sakéu tiwa kϙya n’di n’ϙwa ni n’gbé n’lé ẹ oni

6 Sakéu ti kϙya-kϙya n’ϙf’ayϙ gbaa

7 Yé aya ri bẹ ẹ aya bẹsi ki kϙkonun gudu-gudu ya, n’aya fϙ ni : ϙlϙ ϙlϙ gbé n’lé ϙkonin ẹlẹsẹ kan

8 Ama Sakéu dio liwaju Ϙluwa, a fϙfu ni : yéni ẹ, maa mu idaji n’kan yé mϙnin ya ẹ fu ϙliya ya, ni b’oséni mo di oniankan sisi man san pada fu n’ϙna mẹin

9 Jésu fϙfύ ni : igbala wϙ lϙsϙ ilé yé oni, n’di ni ẹnin yé gbo ni ϙma Abrahamu

10 n’di n’ϙma onian wa kϙwa wo ni kϙgba n’kan yé ti ra ya ẹ la

 

 

Votre encouragement nous est précieux

Vos témoignages contribuent à rendre possibles des sites web tels que celui-ci.