Á dé ϙdon ibilẹ wa bibϙ ya fu yẹ n'mini. Á bébi n'di yẹ ni kéfuwa wa l'alayé bibϙ ya, bi ẹ ma bibϙ ya kéfu nin wa fu wa.
- N'Kaboli, Géngélé nibi abϙliya
Ϙjẹ ϙdon ipadé kan gbo a jẹ l'ϙsin ékéji osu ẹkẹjon ϙdon ẹ ni. A dé asiko isu titon. A péi ϙma kabϙli ya gudu gudu n'di kidi yé an wa. N'kan yé ϙdon yé wa fu ẹ, akusin ni : ko péi ϙma àná ya jon, n'anka yéni kéi ni n'kan yé afa ilu nañi, ni an ka yéni kéi ni n'kan yé n'ko mu ilu lϙ liwaju n'ϙna owó kisé, éto ibilẹ, n'ϙna suku kilϙ, n'ϙna politiki, n'ϙna n'kan oko ya un bẹ bẹ lϙ. Ayéma isi isi ya a wayé l'odé yatϙ fu ϙdon l'ϙsϙ ilé ya.
L'akusin, ϙdon yé á fϙ ni á mon ϙti géngélé ni. Ϙjẹ asiko kan yé a wa fu dupẹ fu orisa ilu ya, an sé ẹbϙ ya ka fu ki orisa ilu fu yé asé fu ϙma àná ya ni an ka fu bébi ti ϙdon titon yé a wa ẹ.
- N'Goubi, Agodobi
L'akusin an jẹ a jẹ́ un géngélé sukú ni. Agodobi gbo jẹ ϙdon ipadé kan. A péi ϙma Gubi ya gudu gudu n'di kidi yé an wa ẹ. N'kan yé ϙdon yé wa fu ẹ, akusin ni : ko péi ϙma àná ya jon, n'anka yéni kéi ni n'kan yé afa ilu nañi, ni an ka yéni kéi ni n'kan yé n'ko mu ilu lϙ liwaju n'ϙna owó kisé, éto ibilẹ, n'ϙna suku kilϙ, n'ϙna politiki, n'ϙna n'kan oko ya un bẹ bẹ lϙ. Ayéma isi isi ya a wayé l'odé yatϙ fu ϙdon l'ϙsϙ ilé ya.