Ijo Àná ya

N'kabϙli un Gubi

  • Igbalẹ

Igbalẹ ni ijo kan yé an fu jo gẹlẹdẹ. Ama an tiko a jò l'aémadi égi. An lϙ n'gbalẹ fu pédi gẹlẹdẹ. An tiku a jó fu s'iku.

  • Gẹlẹdẹ

Gẹlẹdẹ ni ijo kan yé an wu égi fu jo ẹ.

  • Tooki

Jϙjϙ, tooki ni ijo ayéma osupa fu ϙma égidan ya. An p'awϙ fu jó ni.

  • Kolobi

Ijo olo isa ya ni.

Danseuses exécutant la danse kolobi

  • Akoto

Akoto ni ijo kan yé an jo gbo an ké añi bẹni asoki gbo ẹ. Ama aran ẹ yatϙ. Akoto ni aran tẹ.

  • Atimbali

Ijo arϙ Takété n'kaboli. Ϙjẹ ijo kan gbo an jo fu s'iku ẹ ni. Bi an jò, á gu ϙma Takété ya, n'di bẹ n'an fϙ ni ijo arϙ Takété ni. An fan ipé.

  • Assoki un Jipo

Ijo ibilẹ ni, kijo ẹ jẹ ϙna kan so. 

  • Waya

Onri ni.

Votre encouragement nous est précieux

Vos témoignages contribuent à rendre possibles des sites web tels que celui-ci.